Posts

Showing posts from 2015

Mo N Tesiwaju Lona Na

Author: Johnson Oatman Jr (1856-1952) Mo n te siwaju lona na Mo n goke si lojojumo Mo n gbadura bi mo ti n lo Oluwa jo gbe mi soke Refrain: Oluwa jo gbe mi soke Fami lo si ibi giga Apata to ga jumi lo Oluwa jo gbe mi soke Ife okan mi ko duro Larin 'yemeji at'eru Awon miran le ma gbe'be Ibi giga lokan mi fe Mo fe ki nga ju aye lo Ninu ogo didan julo Mo ngbadura ki nle de 'be Oluwa mumi de 'le na. Fa mi lo si ibi giga L’aisi Re nko ni le de 'be Fa mi titi d’oke orun Ki nkorin lat'ibi giga. I’m pressing on the upward way, New heights I’m gaining every day; Still praying as I onward bound, “Lord, plant my feet on higher ground.” Refrain: Lord, lift me up, and let me stand By faith on Canaan’s tableland; A higher plane than I have found, Lord, plant my feet on higher ground. My heart has no desire to stay Where doubts arise and fears dismay; Though some may dwell where these abound, My prayer, my aim, is higher gr

Nigba Igbi Aye Ba Dide Si O / Ro 'Bukun Re / Count Your Blessings

Author: Johnson Oatman Jr (1856-1952) Nigba igbi aiye ba dide si o, T' okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y'o ya o fun nkan t' Oluwa t'se. Refrain Ro 'bukun re ka won lokokan, Ro ohun t' Olorun se fun o; Ro 'bukun re, ka won lokokan, Ro 'bukun re, ri nkan t' Olorun ti se. Eru aniyan ha ti n pa okan re? Agbelebu ti 'wo nru ha si wuwo? Siro ibukun re le 'yemeji lo, Iwo y'o si korin b' ojo ti nkoja. Nigbat' ini elomi kun o loju, Ranti Krist n 'oro aimoye fun o, Siro ibukun re t' owo ko le ra, At' ere re lorun, ile re l' oke Beni larin ija b' o ti wu ko ri, Mase ba okan je mo p' Olorun mbe, Siro ibukun re, Angeli y'o wa, Fun ranwo on 'tunu d'opin ajo re. Source: YBH #658 When upon life’s billows you are tempest tossed, When you are discouraged, thinking all is lost, Count your many blessings name them one by one, And it will surp

Olorun Awa Fe / We Love The Place, O God

Olorun awa fe, Ile t' ola Re wa; Ayo ibugbe Re Ju gbogbo ayo lo. Ile adura ni, Fun awon omo Re Jesu si wa nibe, Lati gbo ebe won. Awa fe ase Re, Ti nte okan l' orun Iwo l' onje iye, Ti onigbagbo nje. Awa fe oro Re, Oro alafia T' itunu at 'iye Oro ayo titi. Awa fe orin Re, Ti a nko l' aiye yi; Sugbon awa fe mo, Orin ayo t' orun. Jesu Oluwa wa, Busi 'fe wa nihin; Mu wa de 'nu ogo, Lati yin O titi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #42 We love the place, O God, in which your honour dwells: the joy of your abode, all earthly joy excels. We love the house of prayer: for where Christ's people meet, our risen Lord is there to make our joy complete. We love the word of life, the word that tells of peace, of comfort in the strife and joys that never cease. We love the cleansing sign of life through Christ our Lord, where with the name divine we seal the child of God. We love the holy feast where, nourishe

Wo Bo Ti Dun To Lati Ri

Wo! b' o ti dun to lati ri Awon ara t' o re; Ara ti okan won s' okan, L' egbe ide mimo. 'Gba isan 'fe t' odo Krist' sun, O san s' okan gbogbo; 'Lafia Olodumare Dabo bo gbogbo re. O dabi ororo didun, Ni irugbon Aaron'; Kikan re m' aso re run ' re O san s' agbada re. O dara b' iri owuro T' o nse s' oke Sion', Nibit' Olorun f' ogo han, T' O m' ore-ofe han. Behold, how good a thing it is, and how becoming well, Together such as brethren are in unity to dwell! Like precious ointment on the head, that down the beard did flow, Ev’n Aaron’s beard, and to the skirts, did of his garments go. As Hermon’s dew, the dew that doth on Sion’ hills descend: For there the blessing God commands, life that shall never end. Scottish Psalter and Paraphrases, 1650

Yin Oluwa, Oro Didun

Yin Oluwa, oro didun Yin oru 'dake je, Gbogbo aiye so ogo Re, Yin, irawo 'mole. Yin, enyin iji t' o dide N' igboran s' ase Re K' oke at' igi eleso Dapo yin Oluwa. E fi ete nyin mimo yin Enyin ogun orun; Ogo, ola at' agbara Fun Oba 'yeraiye. Eyin, enyin mimo ti nyo Nihin. Nin 'ase Re Orun adura eniti Nt' ori pepe g' oke E yin gbogbo ise Re ti O wa n' ikawo Re, Oluwa, ola Re ti to! Okan mi yin l' ogo. Praise ye the Lord on the glad morning, Praise ye the silent night. All the earth speak of all Thy great glory, Praise Him star and light. Praise Him all the rising great storm, In obedience to His will, Let all the mountains and all the forest, All join to praise Him. All praise Him with your holy tongue, Praise Him all angels above, Glory, power, might and adoration, To the mighty God. Praise Him, praise Him all the holy tongue, Here in His sanctuary. The sweet smell of your supplications,

E Tun Won Ko Fun Mi Ki N Gbo (Wonderful Words Of Life)

Author: P. P. Bliss E tun won ko fun mi ki ngbo Oro 'yanu t' Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro 'yanu t' Iye, Oro iye at' ewa, ti mko mi n' igbagbo! Refrain: Oro didun! Oro 'yanu Oro didun! Oro 'yanu Oro 'yanu t' Iye. Oro 'yanu t' Iye. Kristi nikan lo fi fun ni Oro 'yanu t' Iye! Elese gbo 'pe ife na Oro 'yanu t' Iye, L' ofe la fifun wa, ko le to wa s'orun Gbo ohun ihinrere na, Oro 'yanu t' Iye! F' igbala lo gbogbo enia Oro 'yanu t' Iye, Jesu Olugbala, we wa mo titi lai! Source: Yoruba Baptist Hymnal # 615 Sing them over again to me, Wonderful words of life; Let me more of their beauty see, Wonderful words of life; Words of life and beauty, Teach me faith and duty: Refrain: Beautiful words, wonderful words, Wonderful words of life; Beautiful words, wonderful words, wonderful words of life. Christ, the blessed One, gives to all Wonderful words of lif

Yin Oluwa, Orun Wole

Author: Franz Joseph Hadyn Yin Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l' oke K' orun at' osupa ko, K' awon 'rawo f' iyin fun. Yin Oluwa, O ti s' oro, Awon aiye gb' ohun Re, Fun nwon O fi ofin le'le, T' a ko le baje titi. Yin, nitoriti O l' ola, Ileri Re ko le yi; O ti mu awon enia Re Bori iku on ese. Yin Olorun igbala wa, Ogun orun, so pa Re, Orun, aiye, gbogbo eda, Yin, k' e gb' oruko Re ga. Praise the Lord! O heavens adore him, Praise him, angels in the height; Sun and moon, bow down before him; Praise him, shining stars of light. Praise the Lord, for he hath spoken; Worlds his mighty voice obeyed; Laws which never shall be broken for their guidance he has made. Praise the Lord, for he is gracious; Never shall his promise fail. God has made his saints victorious; Sin and death shall not prevail. Praise the God of our salvation; Hosts on high, his power proclaim; Heaven and earth, and all creation

Ileri Mimo, Jesu N'temi

Words: Fanny Jane Crosby Ileri mimo, Jesu n'temi; Adun ogo nla, orun didan; Ajogun igbala, omo Olorun; Omo Emi ta fi eje we. Refrain: Eyi nitan mi, atorin mi Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo, Eyi nitan mi, atorin mi- Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo. Ijewo mimo, ayo didun Iran ayo nla 'be niwaju mi Angel' sokale lati orun Pelu iyin, ayo at'ife Ijewo mimo, mo r'isinmi Ninu Oluwa, mo r'ibukun Mo duro, mo n sona mo n woke Mo kun fun ore at'ife Re Blessed assurance, Jesus is mine; Oh, what a foretaste of glory divine! Heir of salvation, purchase of God, Born of His Spirit, washed in His blood. Refrain: This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. Perfect submission, perfect delight, Visions of rapture now burst on my sight; Angels descending, bring from above Echoes of mercy, whispers of love. Perfect submission, all is at res

Okan Mi Yin Oba Orun

Words by Henry Francis Lyte Okan mi yin Oba orun Mu ore wa si odo Re; 'Wo ta wosan ta dariji, Ta la ba ha yin bi Re? Yin Oluwa/2x Yin Oba ainipekun. Yin, fun anu t'O ti fihan, Fawon Baba n'nu 'ponju; Yin I, okan na Ni titi, O lora lati binu, Yin Oluwa/2x Ologo n'nu otito. Bi baba ni O ntoju wa, O si mo ailera wa; Jeje l' O ngbe wa l' apa Re, O gba wa lowo ota, Yin Oluwa/2x Anu Re yi aiye ka. A ngba b' itanna eweko, T' afefe nfe, t' o si nro 'Gbati a nwa, ti a si nku, Olorun wa bakanna; Yin Oluwa/2x Oba alainipekun. Angel', e jumo ba wa bo, Enyin nri lojukoju; Orun, osupa, e wole, Ati gbogbo agbaiye, E ba wa yin/2x Olorun Olotito. Source: Yoruba Baptist Hymnal #301 Praise, my soul, the King of heaven; To his feet thy tribute bring. Ransomed, healed, restored, forgiven, Who are me his praise should sing? Alleluia, alleluia! Praise the everlasting King! Praise him for his grace and favour To

A! Mba Le L'egberun Ahon

Author: Charles Wesley A! mba le l' egberun ahon. Fun 'yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re. Jesu t' O s' eru wa d' ayo, T' O mu 'banuje tan; Orin ni l' eti elese, Iye at' ilera. O segun agbara ese O da ara tubu; Eje Re le w' eleri mo, Eje Re seun fun mi O soro oku gbohun Re O gba emi titun Onirobinuje y'ayo Otosi si gbagbo Odi, e korin iyin Re Aditi gbohun Re Afoju, Olugbala de Ayaro fo f'ayo Baba mi at' Olorun mi, Fun mi n' iranwo Re; Ki nle ro ka gbogbo aiye, Ola oruko Re. Source: Yoruba Baptist Hymnal #291 &  Iwe Orin Irapada Ti Ijo Aposteli Na #8 O For a thousand tongues to sing My dear Redeemer's praise! The glories of my God and King, The triumphs of His grace! Jesus! the Name that charms our fears, That bids our sorrows cease; 'Tis music in the sinner's ears, 'Tis life, and health, and peace. He breaks the power of cancell'd sin, He set

Ru Iti Wole

Author: Knowles Shaw Funrugbin l' owuro, irugbin inu 're Funrugbin l' osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati 'gba ikojo A o f' ayo pada, ru iti wole. Refrain: Ru iti wole, ru iti wole A o f' ayo pada ru iti wole Ru iti wole, ru iti wole A o f' ayo pada, ru iti wole. Funrugbin nin' orun, ati nin'ojiji Laiberu ikuku, tabi otutu Nigbati ikore, ati lalaa ba pin A o f' ayo pada, ru iti wole. Bi a tile nf' omije sise f' Oluwa Adanu ta nri le m' okan wa gbogbe Gbat' ekun ba dopin, yio ki wa ku abo A o f' ayo pada, ru iti wole Source: Yoruba Baptist Hymnal #459 Sowing in the morning, sowing seeds of kindness, Sowing in the noontide and the dewy eve; Waiting for the harvest, and the time of reaping, We shall come rejoicing, bringing in the sheaves. Refrain: Bringing in the sheaves, bringing in the sheaves/2x We shall come rejoicing, bringing in the sheaves; Bringing in the sheaves, bringing in the

Mu Won Wa

Alexcenah Thomas , 1885 Olus'aguntan ni npe mi, Kuro nin aginju ese, On p' agutan t' o sako lo Jina rere sinu agbo. Refrain: Mu won wa, mu won wa, Mu won wa, kuro l' oko ese; Mu won wa, mu won wa, M' asako wa sodo Jesu. Ran Olusagutan lowo Lati wa 'gutan re t' o nu, Mu awon t' o nu pada wa, Sin 'agbo kuro l' otutu. Gbo igbe won nin' aginju, Ati lori oke giga, Gb' olusagutan nwi fun o, "Lo mu agutan mi wole." Source: Yoruba Baptist Hymnal #650 Hark! ’tis the Shepherd’s voice I hear, Out in the desert dark and drear, Calling the sheep who’ve gone astray, Far from the Shepherd’s fold away. Refrain: Bring them in, bring them in, Bring them in from the fields of sin; Bring them in, bring them in, Bring the wand’ring ones to Jesus. Who’ll go and help this Shepherd kind, Help Him the wand’ring ones to find? Who’ll bring the lost ones to the fold, Where they’ll be sheltered from the cold? Out

MA FARA FUN'DANWO

Horatio R. Palmer, 1868 Ma f' ara fun 'danwo, nitor' ese ni Isegun kan yio f' ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja Refrain: 'Bere k' Olugbala fi 'Pa oun 'tunu fun o On fe ran o lowo Yio mu o la ja. Ma ko egbe k' egbe, ma soro 'koro Mase pe oruko Olorun l' asan Je eniti nronu at' olotito Ma wo Jesu titi, yio mu o la ja. Olorun yio f' ade f' enit' o segun B' a tile nsubu a fi 'gbagbo segun Olugbala wa yio f' agbara fun wa Ma wo Jesu titi, yio mu o la ja. Source: Yoruba Baptist Hymnal #650 Yield not to temptation, for yielding is sin; Each victory will help you some other to win; Fight manfully onward, dark passions subdue, Look ever to Jesus, He’ll carry you through. Refrain: Ask the Savior to help you, Comfort, strengthen and keep you; He is willing to aid you, He will carry you through. Shun evil companions, bad language disdain, Go

Gba Jesu ba de lati pin ere

Frances J Crosby, 1876 Gba Jesu ba de lati pin ere, B' o j' osan tabi l' oru, Y'o ha ba wa nibit' a gbe ns' ona, Pel' atupa wa tin tan? Refrain: A le wipe a mura tan ara, Lati lo s' ile didan? Yio ha ba wa nibit' a gbe ns' ona? Duro, tit' Oluwa yio fi de? Bi l' owuro, ni afemojumo Ni Yi o pe wa l' okankan; Gbat' a f' Oluwa l' ebun wa pada, Yio ha dahun pe, "O seun?" A s' oto ninu ilana Re, Ti sa ipa wa gbogbo? Bi okan wa ko ba da wa l' ebi, A o n' isimi ogo. Ibukun ni fun awon ti ns' ona, Nwon o pin nin' ogo Re. Bi O ba de l' osan tabi l' oru, Yio ha ba wa n' isona? Source:  Yoruba Baptist Hymnal #573 When Jesus comes to reward His servants, Whether it be noon or night, Faithful to Him will He find us watching, With our lamps all trimmed and bright? Refrain: Oh, can we say we are ready, brother? Ready for the soul’s bright home? Say, will He

Olorun mi boju wo mi

H.F. Hemy Olorun mi bojuwo mi F' iyanu 'fe nla Re han mi; Ma je ki n gbero fun 'ra mi, Tori 'Wo ni n gbero fun mi; Baba mi to mi l'aiye yi Je k' igbala Re to fun mi. Ma je ki mbu le O lowo, 'Tori 'Wo li onipin mi, S' eyi t' Iwo ti pinnu re, Iba je' ponju tab' Oluwa tal' o r' idi Re, Iwo Olorun Ologo? Iwo l' egbegberun ona Nibiti nko ni 'kansoso. B' orun ti ga ju aiye lo, Bel' ero Re ga ju t' emi, Ma dari mi k' emi le lo S' ipa ona ododo Re Source: Yoruba Baptist Hymnal #257 My God beholdeth me Thy child Show thy wonderful love to me; Leave me not alone to my way, For thou art my sole counsellor. Lead me through this world, my father! Let enough thy salvation be. Let me seek thy counsel for all, For thou shall be my only share: Do all that thou hast planned for me, From thy great and sure profound will. Lord, thy existence to the world Can never be comprehended; Th

Oluwa Mi Mo N Jade Lo

Charles Wes­ley, Hymns and Sac­red Po­ems, 1749 . OLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l' emi o mo, L' oro, l' ero ati n' ise. Ise t' O yan mi l' anu Re Je ki nle se tayotayo; Ki nr' oju Re n'nu ise mi, K' emi si fi ife Re han. Dabobo mi lowo 'danwo, K' O pa okan mi mo kuro Lowo aniyan  aiye yi, Ati gbogbo ifekufe. Iwo t'oju Re r' okan mi, Ma wa lowo otun mi lai, Ki nma sise lo l' ase Re, Ki nf' ise mi gbogbo fun O. Jeki nreru Re t'o fuye, Ki nma sora nigbagbogbo, Ki nma f' oju si nkan t' orun, Ki nsi mura d' ojo ogo. Ohunkohun t' O fi fun mi, Jeki nle lo fun ogo Re, Ki nf' ayo sure ije mi, Ki mba O rin titi d' orun. Source: Yoruba Baptist Hymnal #56 Forth in Thy Name, O Lord, I go, My daily labor to pursue; Thee, only Thee, resolved to know In all I think or speak or do. The task Thy wisdom hath assigned, O let me cheerfully fulfill; In a

Wo! Gbogbo Ile Okunkun

Author unknown WO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T' ojo ayo t'o l' ogo; Ojo Ayo! K' owuro re yara de! Ki India oun Afrika, K' alaigbede gbogbo ri Isegun nla t' o l' ogo ni, T' ori oke Kalfari: K' ihinrere Tan lat' ilu de ilu. Ijoba t' o wa l' okunkun, Jesu, tan 'mole fun won. Lat' ila-orun de 'wo re, K' imole le okun lo; K' irapada Ti a gba l' ofe bori. Ma tan lo, 'wo ihinrere, Ma segun lo, ma duro: K' ijoba re aiyeraiye Ma bi si, k' o si ma re; Olugbala Wa, joba gbogbo aiye. Millions groping yet in darkness Think, my heart and be thou still! Each of God's own promise tells us Of a glorious happy morn Day of gladness, day of gladness, May that day dawn on me soon Let all India and Africa Men of different tribes and creed Know the great and glorious vict'ry Freely giv'n on Calvary May the Gospel, may the Gospel, B

Iwo Ti Gbogbo Eda N Sin

Iwo ti gbogbo eda nsin L' ara erupe yi, Bi O tit obi to l'aiye! B' ogo Re ti po to!   Nigbati mo f' iyanu wo Ogo 'se Re l' oke, Osupa ti njoba l' oru, At' irawo tin tan.   Oluwa kil' enia ti 'Wo fe ma ronu re? Tab' iran re t' Iwo 'ba ma S ore to to yi fun?   Iwo ti gbogbo eda nsin L' ara erupe yi, Bi O tit obi to l' aye! B' ogo Re ti po to.

Igba Wa N Be Lowo Re

Words: Will­iam F. Lloyd, in the Tract Mag­a­zine, March 1824 . Igba wa mbe li owo Re, A fe ko wa nibe; A fi emi at' ara wa Si abe iso Re. Igba wa mbe li owo Re, Awa o se beru? Baba ki y'o je k' omo Re, Sokun li ainidi. Igba wa mbe li owo Re, 'Wo l' a o gbekele; Tit' a o f' aiye osi 'le T' a o si r' ogo Re. Igba wa mbe li owo Re Ngo ma simi le O, Lehin iku, low, otun Re. L' em o wa titi lai. Source: Yoruba Baptist Hymnal #328 My times are in Thy hand; My God, I wish them there; My life, my friends, my soul I leave Entirely to Thy care. My times are in Thy hand; Whatever they may be; Pleasing or painful, dark or bright, As best may seem to Thee. My times are in Thy hand; Why should I doubt or fear? My Father’s hand will never cause His child a needless tear. My times are in Thy hand, Jesus, the crucified! Those hands my cruel sins had pierced Are now my guard and guide. My times are in Thy hand,

Oluwa, Mo Gbo Pe Iwo

Words: Elizabeth Codner, 1860 Oluwa, mo gbo pe Iwo Nro ojo 'bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s' ori mi. An' emi! Ro ojo re s' ori mi! Ma koja Baba Olore, Bi ese mi tile po; 'Wo le fi mi sile, sugbon Jek' anu Re ba le mi. An' emi, etc. Ma koja mi, Olugbala Jek' emi le ro mo O; Emi nwa oju rere Re, Pe mi mo awon t' O npe. An' emi, etc. Ma koja mi, Emi Mimo, 'Wo le la 'ju afoju; Eleri itoye Jesu, Soro ase na si mi. An' emi, etc. Mo ti sun fonfon nin' ese, Mo bi O binu koja; Aiye ti de okan mi, jo Tu mi, k' o dariji mi. An' emi, etc. Ife Olorun ti ki ye; Eje Krist' iyebiye; Ore-ofe alainiwon; Gbe gbogbo re ga n'nu mi. An' emi, etc. Ma koja mi, dariji mi, Fa mi mora, Oluwa; 'Gba O nf' ibukun f' elomi, Ma sai f' ibukun fun mi. An' emi, etc. Lord, I hear of showers of blessing, thou art scattering full and free; showers the thirsty land refr

Gbadura Wa Oluwa

Gb'adura wa Oluwa, F' awon omo t' O fun wa, Pin wa ninu 'bukun Re, Si fun won l' ayo l' orun. Je k' okan won sunmo O, Nigba won wa l' omode, Je ki nwon f' ogo Re han, L' akoko 'gba ewe won. Fi eje Olugbala, We okan won mo toto; Je k' a tun gbogbo won bi, Ki nwon si le je Tire. Anu yi l' a mbebe fun, K' O si gbo adura wa; Iwo l' a gb' okan wa le, Ni anu gb' adura wa. Amin. Hearken to our prayer O Lord, For thes children you give us; Bestow on them Your full blessing, Heavenly joy impart to them. Let their hearts to Thee draw nigh, As they’re tender in age; Let Your glory in them shine, In their days of infancy. With the precious Blood of Christ, Sanctify their soul spot-clean; Grant them to be born anew, That they may be wholly Thine. This mercy we crave O Lord, Hearken to our petition; In Thee we repose confidence, Graciously answer prayer.

Ogo F'Olorun Lale Yii

Text: Thomas Ken, 1637-1710 Music: Thomas Tallis, c. 1505-1585 Ogo f'Olorun l' ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re Oluwa, f' ese mi ji mi, Nitori Omo Re loni; K' emi le wa l' Alafia Pelu Iwo ati aiye. Ko mi ki nwa, kin le ma wo Iboji t'emi b' eni mi; Ko mi, ki nku, kin le dide Ninu ogo l' ojo 'dajo. Je k' okan mi le sun le O K' orun  didun p' oju mi de; Orun ti y'o m' ara mi le Ki nle sin O li owuro. Bi mo ba dubule laisun, F' ero orun kun okan mi Ma je ki nl' ala buburu Ma je k' ipa okun bo mi. Yin Oluwa, gbogbo eda Ti mbe n' isale aiye yi; E yin l' oke, eda orun, Yin Baba, Omo on Emi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #71 Glory to thee, my God, this night, For all the blessings of the light: Keep me, O keep me, King of kings, Beneath thine own almighty wings Forgive me, Lord, for thy dear Son, the ill that I this day have

Ji Okan Mi Ba Oorun Ji

Words: Thomas Ken Ji okan mi ba oorun ji, Mura si ise ojo re; Mase ilora, ji kutu, Ko san gbese ebo ooro. Ogo fun Enit'o so mi, To tu mi lara loj'oorun; Oluwa ijo mo ba ku, Ji mi saye ainipekun. Oluwa mo tun eje je, Tu ese ka biri ooro; So akoronu mi oni, Si f'Emi Re kun inu mi. Oro atise mi oni, Ki won le ri bi eko Re; Kemi fi ipa mi gbogbo Sise rere fun ogo Re. Source: YB Hymnal #47 Awake, my soul, and with the sun Thy daily stage of duty run; Shake off dull sloth, and joyful rise, To pay thy morning sacrifice. Thy precious time misspent, redeem, Each present day thy last esteem, Improve thy talent with due care; For the great day thyself prepare. By influence of the Light divine Let thy own light to others shine. Reflect all Heaven’s propitious ways In ardent love, and cheerful praise. In conversation be sincere; Keep conscience as the noontide clear; Think how all seeing God thy ways And all thy secret thoughts surveys. Wak

Isun Kan Wa To Kun Feje

William Cowper, 1731-1800 Isun kan wa to kun feje, O yo niha Jesu. Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. Gba mo figbagbo risun naa, Ti n san fun ogbe Re, Irapada dorin fun mi Ti n o ma ko titi. Ninu orin to dun ju lo, Lemi o korin Re: 'Gba t'akololo ahon yii Ba dake niboji. Mo gbagbo p'O pese fun mi (Bi mo tile saiye) Ebun ofe ta feje ra, Ati duru wura. Duru ta towo'Olorun se, Ti ko ni baje lai: T'a o ma fi yin Baba wa, Oruko Re nikan. Source: YB Hymnal #232 There is a fountain filled with blood, Drawn from Immanuel’s veins, And sinners plunged beneath that flood Lose all their guilty stains: The dying thief rejoiced to see That fountain in His day; And there may I, though vile as he, Washed all my sins away: Dear dying Lamb, Thy precious blood Shall never lose its pow’r, Till all the ransomed church of God Are safe, to sin no more: E’er since by faith I saw the stream Thy flowing wounds supply, Redeeming love has been

Laifoya Lapa Jesu

By Frances J. Crosby , 1868 Laifoya lapa Jesu, Laifoya laya Re Labe ojiji 'fe Re Lokan mi yo sinmi. Gbo ohun angeli ni, Orin won deti mi, Lati papa ogo wa, Lati okun Jaspi. Refrain: Laifoya lapa Jesu Laifoya laya Re Labe ojiji 'fe Re Lokan mi yo sinmi. Laifoya lapa Jesu Mo bo low'aniyan, Mo bo lowo idanwo, Ese ko nipa mo, Mo bo lowo 'banuje, Mo bo lowo eru O ku idanwo die! O k'omije die! Jesu abo okan mi, Jesu ti ku fun mi, Apata ayeraye Lemi o gbekele, Nihin lemi o duro Tit'oru yo koja, Titi n o fi rimole Ni ebute ogo. Source: Yoruba Baptist Hymnal #254 Safe in the arms of Jesus, Safe on His gentle breast; There by His love o’ershaded, Sweetly my soul shall rest. Hark! ’tis the voice of angels Borne in a song to me, Over the fields of glory, Over the jasper sea. Refrain: Safe in the arms of Jesus, Safe on His gentle breast; There by His love o’ershaded, Sweetly my soul shall rest. Safe in the arms of Jes

Ninu Gbogbo Ewu Oru

Image
Thomas Kelly, 1769-1855 Ninu gbogbo ewu oru, Oluwa l'O n so wa; Awa si tun rimole yii, A tun te ekun ba. Oluwa pa wa mo loni, Fi apa Re so wa, Kiki awon t'Iwo pa mo, Lo n yo ninu ewu. Koro wa ati iwa wa, Wipe, Tire l'awa; To bee kimole otito Le tan loju aye. Ma je ka pada lodo Re, Olugbala owon; Titi a o foju wa ri Oju Re nikehin. Source: Yoruba Baptist Hymnal #232 Through all the dangers of the night, Preserv'd, O Lord! By thee; Again we hail the cheerful light, Again we bow the knee. Preserve us, Lord! throughout the day, And guide us by thy arm; For they are safe, and only they, Whom thou preserv'st from harm. Let all our words and all our ways, Declare that we are thine, That so the light of truth and grace Before the world may shine. Let us ne'er turn away from thee; Dear Saviour, hold us fast, Till with immortal eyes, we see Thy glorious face at last.

Wa Obirin E Ko

Wa obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist' 'Mole Olorun Krist' to jinde nipa, Krist' t'O de yin lade, Oun ni k'eyin. E ko awon 'mode Ati arabinrin Nile gbogboFun awon elese Fawon alailera Ateni okunkun Magbadura. Sise pelu 'gboya Ojumo fere mo Eni ife 'Rawo yo tan fun yin Inu yin yo si dun Ati nipa 'fe Re E ma reti. 'Gbati' kore ba de Aka Oluwa wa Yio kun pupo 'Reti Onirele Krist' ti gbogbo wa n wa, Krist' yo fun yin lere Pelu ayo Come, women, wide proclaim Life through your Savior slain; Sing evermore. Christ, God’s effulgence bright, Christ, who arose in might, Christ, who crowns you with light, Praise and adore. Come, clasping children’s hands, Sisters from many lands, Teach to adore. For the sin sick and worn, The weak and overborne, All who in darkness mourn, Pray, work, yet more. Work with your courage high, Sing of the daybreak nigh, Your love outpour. Stars shall

Jesu Fe K'emi Je 'mole

Nellie Talbot Jesu fe k'emi je 'mole Ki n tan lojoojumo Nibi gbogbo ki n le wun Oun, Nile, ni skul, lode. Refrain: Imole, imole, Jesu fe kemi je 'mole Imole, imole, Lemi yo je fun Jesu. Jesu fe ki emi feran, Gbogb'ohun ti mo ri, Ki n fi itara atayo, Tomode Re le je. Mo le semole fun Jesu, Bi mo ba gbiyanju; Ki n si sin Oun nigba gbogbo, Ki n ba Oun gbe orun. Source: Yoruba Baptist Hymnal #642 Jesus wants me for a sunbeam, To shine for Him each day; In every way try to please Him, At home, at school, at play. A sunbeam, a sunbeam, Jesus wants me for a sunbeam; A sunbeam, a sunbeam, I’ll be a sunbeam for Him. Jesus wants me to be loving, And kind to all I see; Showing how pleasant and happy His little one can be. I will ask Jesus to help me To keep my heart from sin, Ever reflecting His goodness, And always shine for Him. I’ll be a sunbeam for Jesus; I can if I but try; Serving Him moment by moment, Then live with Him on h

Itan Kan Wa Fawon Orile

H. Ernest Nichol, 1896 Itan kan wa fawon orile Ti yo tun okan won se Itan otito, ti o si dun Itan alafia, oun'mole, Itan alafia, oun'mole. Refrain: Tori okunkun yo di oye Oye yo dosan gangan Ijoba nla Krist' yo gba aye 'Joba ife ati'mole A lorin kan ko f'orilede, Ti wo gbokan won s'Oluwa, Orin ta fi segun Esu, A o se oko, a o si run'da, A o se oko, a o si run'da. A ni ise kan je forile-ede, P'Oluwa to joba loke, Ti ran 'Mo Re lati gba wa la, O fi han wa pe 'Fe l'Olorun Pe Ife ni Olorun. A l'Olugbala kan fi han 'raye, En' t'O koja nu 'banuje, Ki gbogbo eniyan agbaye Le gb' otito oro Olorun, Le gb' otito oro Olorun. Source: Yoruba Baptist Hymnal #642 We’ve a story to tell to the nations, That shall turn their hearts to the right, A story of truth and mercy, A story of peace and light, A story of peace and light. For the darkness shall turn to dawning, And the dawni

Gbo Ohun Jesu Ti N Ke Pe

Author: Daniel March , 1868. Gbo ohun Jesu ti n ke pe, Tani yoo sise loni? Oko pon pupo fun 'kore, Tani yi o lo ka a? Kikankikan l'Oluwa npe Ebun nla lo fi fun o. Tani yo fayo dahun pe, "Emi ni'i ran mi, ran mi." Biwo ko le la okun lo, Lati wa 'won keferi, O le ri won nitosi re, Won wa lenu ona re; Bo ko le fi wura tore, O le fi baba tore, Die to si se fun Jesu, 'Yebiye ni loju Re. Bo ko le soro b'angeli, Bo ko le wasu bi Paul' Iwo le so tife Jesu, O le so ti iku re; Biwo ko le ji elese Ninu ewu idajo, 'Wo le ko awon omode Li ona t'Olugbala. Biwo ko le kagbalagba, Krist' Olusaguntan ni, "Bo awon od'-aguntan Mi Gbe ounje ti won lodo," O le je pe awon 'mode To ti fi owo re to, Ni yoo wa larin oso re Gbat'o ba de'le rere. Ma jek'eniyan gbo wipe, "Ko si nkan temi le se," Nigba twon keferi nku, Ti Oluwa si n pe o, Fayo gba ise t'O pe o Kise Re je ayo r

Mo J'alejo Nihin

Author: Elijah T. Cassel (1902) Mo j’alejo nihin, 'nu ile ajeji, Ile mi jin rere, lor'ebute wura; Lati je iranse n'koja okun lohun Mo n sise nihin f'Oba mi. Refrain: Eyi nise ti mo wa je, 'Se tawon angel' nko lorin E b'Olorun laja l'Oluwa Oba wi E ba Olorun yin laja. Eyi lase Oba, keniyan n'bi gbogbo Ronupiwada kuro ninu 'dekun ese, Awon to ba gboran yio joba pelu Re, Eyi nise mi f'Oba mi. Ile mi dara ju petele Sharon lo, Nibiti 'ye ainipekun atayo wa; Ki n so fun araye, bi won se lee gbebe Eyi nise mi f'Oba mi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 I am a stranger here, within a foreign land; My home is far away, upon a golden strand; Ambassador to be of realms beyond the sea, I’m here on business for my King. Refrain This is the message that I bring, A message angels fain would sing: “Oh, be ye reconciled," Thus saith my Lord and King, “Oh, be ye reconciled to God." This is the King’s co

Mo Ti N Bese Rin Tipe

Author Unknown Mo ti n bese rin tipe Pin wa niya Oluwa Ore 'parun ni tire Gba mi Jesu, mo segbe. Ko sanfani ti mo ri Lara ati lokan mi, Gbogbo re lo dibaje Jesu gba mi, mo segbe. Moriye nin'oro Re Ibagbe Re si wu mi, Ese di mi mu sinsin, Gba mi Jesu, jo gba mi. O ha dake ki n segbe, Nitori ailera mi? O ha jowo mi fese? Ka ma ri, Jesu gba mi. Iwo to rinu, rode, Iyanju mi han si O, O mo bi mo ti n ja to, O romije 'koko mi. Ese fi ewon de mi, Da mi, Oluwa da mi, Iwo ni n o sin titi, Jesu Olugbala mi. I have walk'd with sin so long, Seperate us, Saviour, Lord Friend of destruction is he Save me Jesus or I die There's no benefit I find Within my heart and body All of them are quite corrupt Save me Jesus or I die I find life within Thy word Thy communion is so sweet Sin doth hold me fast, O Lord Save me Jesus, do save me Will Thou silently watch me Till I die 'cause of weakness Will Thou leave me unto sin God forbi

Aigbagbo Bila

Author:  John Newton Aigbagbo bila! Temi l'Oluwa Oun o si dide fun igbala mi, Ki n sa ma gbadura, Oun o se 'ranwo: 'Gba Krist' wa lodo mi, ifoya ko si. Bona mi ba su, Oun l'O sa n to mi, Ki n sa gboran sa, Oun o si pese; Biranlowo eda gbogbo ba saki, Oro tenu Re so yo bori dandan. Ife to n fi han, ko je ki n ro pe, Yo fi mi sile ninu wahala; Iranwo ti mo si n ri lojojumo, O n ki mi laya pe emi o la a ja. Emi o se kun tori iponju, Tabi irora? O ti so tele! Mo moro Re pawon ajogun 'gbala, Wo ko le sai koja larin wahala. Eda ko le so kikoro ago T'Olugbala mu kelese le ye; Aye Re tile buru ju temi lo, Jesu ha le jiya, kemi si ma sa. Nje bohun gbogbo ti n sise ire, Adun nikoro, ounje li oogun; Boni tile koro, sa ko ni pe mo, Gbana orin 'segun yio ti dun to! Source: Yoruba Baptist Hymnal #330 Begone, unbelief;  my Savior is near, and for my relief  will surely appear; by prayer let me wrestle,  and he will perform; with

Ki Lo Le Wese Mi Nu

Image
Robert Lowry, pub.1876 Ki lo le wese mi nu? Ko si lehin eje Jesu; Ki lo tun le wo mi san? Ko si lehin eje Jesu. Refrain: A! Eje 'yebiye To mu mi fun bi sno, Ko sisun miran mo, Ko si lehin eje Jesu. Fun 'wenumo mi, nko ri, Nkan mi lehin eje Jesu; Ohun ti mo gbekele Fun 'dariji, leje Jesu. Etutu fese ko si, Ko si lehin eje Jesu Ise rere kan ko si Ko si lehin eje Jesu Gbogbo igbekele mi, Ireti mi leje Jesu; Gbogbo ododo mi ni Eje, kiki eje Jesu. br /> Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 What can wash away my sin? Nothing but the blood of Jesus; What can make me whole again? Nothing but the blood of Jesus. Oh! precious is the flow That makes me white as snow; No other fount I know, Nothing but the blood of Jesus. For my pardon, this I see, Nothing but the blood of Jesus; For my cleansing this my plea, Nothing but the blood of Jesus. Nothing can for sin atone, Nothing but the blood of Jesus; Naught of good that I have d

Fa Mi Mora

Words: Fanny Crosby Tire lemi se, mo ti gbohun Re O nso ife Re si mi. Sugbon mo fe n'de lapa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O Refrain: Fa mi mora, mora, Oluwa Sib'agbelebu t'O ku Fa mi mora, mora, mora Oluwa Sib'eje Re to niye Ya mi si mimo fun ise Tire, Nipa ore-ofe Re: Je ki n fi okan igbagbo woke, Kife mi te siTire. A! Ayo mimo ti wakati kan Ti mo lo nib'ite Re; 'Gba mo gbadura si Olorun mi, Mo ba soro bi ore, Ijinle ife nbe ti ko le mo Titi n o koja odo Ayo giga ti emi ko le so Titi n o fi wa simi, Source: Yoruba Baptist Hymnal #230 I am Thine, O Lord, I have heard Thy voice, And it told Thy love to me; But I long to rise in the arms of faith And be closer drawn to Thee. Draw me nearer, nearer blessed Lord, To the cross where Thou hast died. Draw me nearer, nearer, nearer blessèd Lord, To Thy precious, bleeding side. Consecrate me now to Thy service, Lord, By the power of grace divine; Let my soul look up with a steadfa

E fun'pe naa kikan

Text: Charles Wesley, 1707-1788 E fun'pe naa kikan Ipe ihinrere Ko dun jake jado Leti gbogbo eda; Odun idasile ti de, Pada, elese, e pada Fun 'pe t'Odaguntan Ta ti pa setutu; Je ki agbaye mo Agbara eje Re. Eyin eru ese, E sora yin d'omo, Lowo Kristi Jesu E gba ominira yin. Olori Alufa L'Olugbala i se O fira Re rubo Arukun aruda Okan alare wa, Simi laya jesu: Onirobinuje, Tujuka si ma yo. Blow ye the trumpet, blow! The gladly solemn sound let all the nations know, to earth's remotest bound: The year of jubilee is come! The year of jubilee is come! Return, ye ransomed sinners, home Jesus, our great high priest, hath full atonement made; ye weary spirits, rest; ye mournful souls, be glad: Extol the Lamb of God, the all atoning Lamb; redemption in his blood throughout the world proclaim . Ye slaves of sin and hell, your liberty receive, and safe in Jesus dwell, and blest in Jesus live: Ye who have sold for n

Nigba Tidanwo Yi Mi Ka

Image
Author Unknown Nigba tidanwo yi mi ka Tidamu aye mu mi Ti Esu wa bi ore mi Lati wa iparun mi. Egbe: Oluwa jo ma sai pe mi B'O ti p'Adam' n'nu ogba "Pe nibo lo wa elese?" Nigba t'Esu mu 'tanje re Gbe mi g'or'oke aye, To ni ki n teriba foun Kohun aye je temi, N'gba bilisi fi tulasi Fe mu mi yase Re da To duro gangan lehin mi Nileri pe ko si nkan, Nigba ti mo ba fe topa Damoran o'n fe 'nu mi Tokan mi n se kilakilo, Ti n ko tutu, nko gbona, Nigba ti ko salabaro, Tolutunu si jina, Ti 'banuje ja mi gbongbon Bi iyo ninu okun, Nigba bi aja ti ko gbo Fere ti olode mo, Sonu saginju aye lo Lain' ireti ipada, Nigbati igbekele mi Di togun atorisa, Togede di adura mi, Tofo di ajisa mi, Source: YBH #209 When strong temptations surround me And the world's tempest face me, And Satan came like a friend, Pushing strong for me to fall. Refrain: Saviour please fail not to call me As tho

Onisegun Nla Wa Nihin

By: William Hunter Onisegun nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni lara da A! Gbo ohun ti Jesu! Refrain: Iro didun lorin Seraf', Oruko idun ni ahon. Orin to dun julo ni: Jesu! Jesu! Jesu! A fi gbogbo ese re ji o, A! Gbo ohun ti Jesu! Rin lo sorun lalafia, Si ba Jesu de ade. Gbogb'ogo fun Krist' t'O jinde! Mo gbagbo nisisiyi; Mo foruko Olugbala, Mo fe oruko Jesu. Oruko Re leru mi lo Ko si oruko miran; Bokan mi ti n fe lati gbo Oruko Re 'yebiye. Arakunrin, e ba mi yin, A! Yin oruko Jesu! Arabinrin, gbohun soke A! Yin oruko Jesu! Omode at'agbalagba, To fe oruko Jesu, Le gba 'pe 'fe nisisiyi, Lati sise fun Jesu Nigba ta ba si de orun, Ti a ba si ri Jesu, A o ko 'rin yite ife ka, Orin oruko Jesu. Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 The great Physician now is near, The sympathizing Jesus; He speaks the drooping heart to cheer, Oh, hear the voice of Jesus. Sweetest note in seraph song, Sweetest name

Jesu Fe Mi, Emi Mo

Jesu fe mi, emi mo Bibeli so fun mi bee; Tire lawon omode Won ko lagbara, Oun ni. Refrain Ah, Jesu fe mi, Ah, Jesu fe mi, Ah, Jesu fe mi, Bibeli so fun mi . Jesu fe mi, O ti ku Lati si orun sile; Yi o we ese mi nu, Y'o je komo Re wole Jesu fe mi, O fe mi, Bi emi tile saisan, Lor'akete arun mi, O t'ite Re wa so mi. Jesu fe mi, Yi o duro Ti mi lona mi gbogbo: Bi mo ba fe ti mo ku, Yio mu mi rele orun. Poem by Anna Bartlett Warner As originally published in 1860, it appeared in three stanzas, as follows: Jesus loves me—this I know, For the Bible tells me so; Little ones to him belong,— They are weak, but he is strong. Jesus loves me—loves me still, Though I'm very weak and ill; From his shining throne on high, Comes to watch me where I lie. Jesus loves me—he will stay, Close beside me all the way. Then his little child will take, Up to heaven for his dear sake. Hymn by William Batchelder Bradbury   Jesus loves me—this I know,

Okan Mi Yo Ninu Oluwa

Author: E.O. Excell Okan mi nyo ninu Oluwa ‘Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r’oju Re Emi yo ninu Re Emi yo ninu Re Gba 'gbogbo lo fayo kun okan mi ‘Tori emi nyo n’nu Re. O ti pe t’O ti nwa mi kiri ‘Gbati mo rin jina s’agbo O gbe mi wa sile l’apa Re Nibiti papa tutu wa Ire at’anu Re yi mi ka Or’ofe Re n san bi odo Emi Re nto, o si nse ‘tunu O n ba mi lo si ‘bikibi Emi y’o dabi Re ni ‘jo kan N o s’eru wuwo mi kale Titi di ‘gbana n o s’oloto Ni sise oso f’ade Re. Amin. Translated by Ayobami Temitope Kehinde Dec 15, 2018. My soul is so happy in Jesus, For He is so precious to me; His voice it is music to hear it, His face it is heaven to see. Refrain: I am happy in Him, I am happy in Him; My soul with delight He fills day and night, For I am happy in Him. He sought me so long ere I knew Him, When wand’ring afar from the fold; Safe home in His arms He hath bro't me, To where there

Alleluya! Ija D’opin, Ogun Si Tan

Author Unknown Trans f. Latin to English: Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’opin ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo lao ma ko. – Alleluya! Gbogbo ipa n’iku ti lo; Sugbon Kristi f’ogun re ka; Aye ! e ho iho ayo. – Alleluya! Ojo meta na ti koja. O jinde kuro nin’oku: E f’ogo fun Olorun wa. – Alleluya! O d’ewon orun apadi, O silekun orun sile; Ekorin iyin ‘segun Re. – Alleluya! 5. Jesu, nipa iya t’O je, A bo lowo iku titi: Titi la o si ma yin O – Alleluya! Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun. Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Alleluia! He closed the yawning gates of hell, the bars from heaven's high portals fell; let h

E YO N’NU OLUWA, E YO

Words:Mary E. Servoss, in Sacred Songs and Solos, by Ira D. Sankey, 1881. E yo n’nu Oluwa, e yo, Eyin t’okan re se dede Eyin t’o ti yan Oluwa, Le ‘banuje at’aro lo Refrain: Eyo! E yo! E yo n’nu Oluwa, e yo! E yo! E yo! E yo n’nu Oluwa, e yo! E yo ‘tori O'n l’Oluwa L’aye ati l’orun pelu Oro Re bor’ohun gbogbo O l’agbara lati gbala ‘Gbat’ e ba nja ija rere, Ti ota f’ere bori yin Ogun Olorun t’e ko ri Po ju awon ota yin lo B’okunkun tile yi o ka Pelu isudede gbogbo Mase je k’okan re damu Sa gbeke l’Oluwa d’opin E yo n’nu Oluwa, e yo E korin iyin Re kikan Fi duru ati ohun ko Aleluya l’ohun goro. Amin. Be glad in the Lord, and rejoice, All ye that are upright in heart; And ye that have made Him your choice, Bid sadness and sorrow depart. Rejoice, rejoice, Be glad in the Lord and rejoice; Rejoice, rejoice, Be glad in the Lord and rejoice Be joyful, for He is the Lord, On earth and in Heaven supreme; He fashions and rules by His word— The

ASEGUN ATI AJOGUN NI A JE

Image
Author: Mrs C.H. Morris A segun ati ajogun ni a je, Nipa eje Kristi a ni isegun B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu Ko s’ohun to le bori agbara re Asegun ni wa, nipa eje Jesu Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu Eni t’a pa f’elese Sibe, O wa, O njoba Awa ju asegun lo Awa ju asegun lo A nlo l’oruko Olorun Isreal Lati segun ese at’aisododo Kise fun wa, sugbon Tire ni iyin Fun ‘gbala at’isegun ta f’eje ra Eni t’O ba si segun li ao fi fun Lati je manna to t’orun wa nihin L’orun yo sig be imo ‘pe asegun Yo wo ‘so funfun, yo si dade wura. Amin Conquerors and overcomers now are we, Thro’ the precious blood of Christ we've victory, If the Lord be for us, we can never fail; Nothing 'gainst his mighty pow'r can e'er prevail. Conquerors are we, thro’ the blood, thro’ the blood; God will give us victory, thro’ the blood, thro’ the blood, Thro’ the Lamb for sinners slain, Yet who lives and reigns again, More than conquerors are we, More than conqueror

OGO F'OLORUN ALLELUIA!

Words: Fanny Crosby Ko su wa lati ma ko orin ti igbani Ogo f’olorun Alleluia! A le fi igbagbo korin na s’oke kikan Ogo f’olorun Alleluia! Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo Pe ona yi nye wa si, Okan wa ns’aferi Re Nigb’o se a o de afin Oba wa ologo,  Ogo f’olorun Alleluia! Awa mbe n’nu ibu ife t’o ra wa pada, Ogo f’olorun Alleluia! Awa y’o fi iye goke lo s’oke orun Ogo f’olorun Alleluia! Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko, Ogo f’olorun Alleluia! Nibiti a ori Oba ogo n’nu ewa Re Ogo f’olorun Alleluia! Nibe ao korin titun t’anu t’o da wa nde Ogo f’olorun Alleluia! Nibe awon ayanfe yo korin 'yin ti Krist; Ogo f’olorun Alleluia! We are never, never weary Of the grand old song; Glory to God, hallelujah! We can sing it loud as ever, with our faith more strong; Glory to God, hallelujah! O, the children of the Lord Have a right to shout and sing, For the way is growing bright, And our souls are on the wing; We are going by and by To the palace

OJO NLA

Words: Philip Doddridge, refrain from Wesleyan Sacred Harp Ojo ayo l’ ojo ti mo Yan O, 'Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’o si sayo re kakiri. Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki nma sora ki nsi ma yo Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu. A ti pari ise nla naa Emi t'Oluwa O'n temi O fa mi mo si tele O Mo yo lati gba ipe naa. Simi aisokan, okan mi, Simi lori ipinnu yi; Mo ripa to lola nibi, Ayo orun kun mi laya. Orun giga to gbeje mi, Yoo gbo lotun lojojumo, Titi n o fi fibukun fun, Idapo yi loju iku. O happy day, that fixed my choice On Thee, my Savior and my God! Well may this glowing heart rejoice, And tell its raptures all abroad. Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! He taught me how to watch and pray, And live rejoicing every day: Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! O happy bond, that seals my vows To Him Who merits all my love! Let cheerful an